Ẹ́kísódù 30:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Kí ọlọ́rọ̀ má ṣe mú ohun tó ju ààbọ̀ ṣékélì* wá, kí aláìní má sì mú ohun tó kéré síyẹn wá láti fi ṣe ọrẹ fún Jèhófà kí ẹ lè fi ṣe ètùtù fún ẹ̀mí* yín.
15 Kí ọlọ́rọ̀ má ṣe mú ohun tó ju ààbọ̀ ṣékélì* wá, kí aláìní má sì mú ohun tó kéré síyẹn wá láti fi ṣe ọrẹ fún Jèhófà kí ẹ lè fi ṣe ètùtù fún ẹ̀mí* yín.