Ẹ́kísódù 28:9, 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “Kí o mú òkúta ónísì méjì,+ kí o sì fín orúkọ àwọn ọmọkùnrin Ísírẹ́lì sára wọn,+ 10 orúkọ mẹ́fà lára òkúta kan, orúkọ mẹ́fà tó ṣẹ́ kù lára òkúta kejì, bí wọ́n ṣe bí wọn tẹ̀ léra.
9 “Kí o mú òkúta ónísì méjì,+ kí o sì fín orúkọ àwọn ọmọkùnrin Ísírẹ́lì sára wọn,+ 10 orúkọ mẹ́fà lára òkúta kan, orúkọ mẹ́fà tó ṣẹ́ kù lára òkúta kejì, bí wọ́n ṣe bí wọn tẹ̀ léra.