Ẹ́kísódù 1:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Wọ́n ni wọ́n lára gidigidi bí wọ́n ṣe ń mú wọn ṣiṣẹ́ àṣekára, wọ́n ń fi àpòrọ́ alámọ̀ àti bíríkì ṣiṣẹ́, wọ́n sì ń mú wọn ṣe onírúurú iṣẹ́ nínú oko bí ẹrú. Kódà, wọ́n lò wọ́n nílòkulò bí ẹrú láti ṣe onírúurú iṣẹ́ àṣekára.+
14 Wọ́n ni wọ́n lára gidigidi bí wọ́n ṣe ń mú wọn ṣiṣẹ́ àṣekára, wọ́n ń fi àpòrọ́ alámọ̀ àti bíríkì ṣiṣẹ́, wọ́n sì ń mú wọn ṣe onírúurú iṣẹ́ nínú oko bí ẹrú. Kódà, wọ́n lò wọ́n nílòkulò bí ẹrú láti ṣe onírúurú iṣẹ́ àṣekára.+