Ẹ́kísódù 35:27, 28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Àwọn ìjòyè náà mú àwọn òkúta ónísì wá àti àwọn òkúta míì tí wọ́n máa tò sára éfódì àti aṣọ ìgbàyà,+ 28 pẹ̀lú òróró básámù àti òróró tí wọ́n á máa fi tan iná, òróró tí wọ́n á fi ṣe òróró àfiyanni+ àti tùràrí onílọ́fínńdà.+
27 Àwọn ìjòyè náà mú àwọn òkúta ónísì wá àti àwọn òkúta míì tí wọ́n máa tò sára éfódì àti aṣọ ìgbàyà,+ 28 pẹ̀lú òróró básámù àti òróró tí wọ́n á máa fi tan iná, òróró tí wọ́n á fi ṣe òróró àfiyanni+ àti tùràrí onílọ́fínńdà.+