Ẹ́kísódù 37:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ó tún ṣe òróró àfiyanni mímọ́+ àti ògidì tùràrí onílọ́fínńdà,+ ó ro àwọn èròjà rẹ̀ pọ̀ dáadáa.*