Ẹ́kísódù 30:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 “Kí o fi bàbà ṣe bàsíà kan pẹ̀lú ẹsẹ̀ rẹ̀ fún wíwẹ̀;+ kí o gbé e sáàárín àgọ́ ìpàdé àti pẹpẹ, kí o sì bu omi sínú rẹ̀.+ Ẹ́kísódù 38:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Lẹ́yìn náà, ó fi bàbà ṣe bàsíà+ àti ẹsẹ̀ bàsíà náà; ó lo dígí* àwọn obìnrin tí wọ́n ṣètò pé kí wọ́n máa ṣiṣẹ́ ìsìn ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé.
18 “Kí o fi bàbà ṣe bàsíà kan pẹ̀lú ẹsẹ̀ rẹ̀ fún wíwẹ̀;+ kí o gbé e sáàárín àgọ́ ìpàdé àti pẹpẹ, kí o sì bu omi sínú rẹ̀.+
8 Lẹ́yìn náà, ó fi bàbà ṣe bàsíà+ àti ẹsẹ̀ bàsíà náà; ó lo dígí* àwọn obìnrin tí wọ́n ṣètò pé kí wọ́n máa ṣiṣẹ́ ìsìn ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé.