Nọ́ńbà 7:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ní ọjọ́ tí Mósè to àgọ́ ìjọsìn+ náà tán, ó fòróró yàn án,+ ó sì yà á sí mímọ́ pẹ̀lú gbogbo ohun tó wà níbẹ̀, pẹpẹ àti gbogbo ohun èlò rẹ̀.+ Lẹ́yìn tó fòróró yan nǹkan wọ̀nyí, tó sì sọ wọ́n di mímọ́,+
7 Ní ọjọ́ tí Mósè to àgọ́ ìjọsìn+ náà tán, ó fòróró yàn án,+ ó sì yà á sí mímọ́ pẹ̀lú gbogbo ohun tó wà níbẹ̀, pẹpẹ àti gbogbo ohun èlò rẹ̀.+ Lẹ́yìn tó fòróró yan nǹkan wọ̀nyí, tó sì sọ wọ́n di mímọ́,+