Ẹ́kísódù 25:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 “Kí o fi ògidì wúrà ṣe ọ̀pá fìtílà.+ Kí ọ̀pá fìtílà náà jẹ́ iṣẹ́ ọnà tí o fi òòlù ṣe. Kí ìsàlẹ̀ rẹ̀, ọ̀pá rẹ̀, àwọn ẹ̀ka rẹ̀, àwọn iṣẹ́ ọnà rẹ̀, àwọn kókó rubutu rẹ̀ àti àwọn ìtànná rẹ̀ jẹ́ ọ̀kan ṣoṣo.+ Hébérù 9:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Torí wọ́n kọ́ apá àkọ́kọ́ nínú àgọ́, níbi tí ọ̀pá fìtílà,+ tábìlì àti àwọn búrẹ́dì tí wọ́n ń gbé síwájú*+ wà; a sì ń pè é ní Ibi Mímọ́.+
31 “Kí o fi ògidì wúrà ṣe ọ̀pá fìtílà.+ Kí ọ̀pá fìtílà náà jẹ́ iṣẹ́ ọnà tí o fi òòlù ṣe. Kí ìsàlẹ̀ rẹ̀, ọ̀pá rẹ̀, àwọn ẹ̀ka rẹ̀, àwọn iṣẹ́ ọnà rẹ̀, àwọn kókó rubutu rẹ̀ àti àwọn ìtànná rẹ̀ jẹ́ ọ̀kan ṣoṣo.+
2 Torí wọ́n kọ́ apá àkọ́kọ́ nínú àgọ́, níbi tí ọ̀pá fìtílà,+ tábìlì àti àwọn búrẹ́dì tí wọ́n ń gbé síwájú*+ wà; a sì ń pè é ní Ibi Mímọ́.+