5 Kí o wá kó àwọn aṣọ náà,+ kí o sì wọ aṣọ àwọ̀tẹ́lẹ̀ fún Áárónì, pẹ̀lú aṣọ àwọ̀lékè tí kò lápá tó máa wà lábẹ́ éfódì, kí o wọ éfódì náà fún un àti aṣọ ìgbàyà, kí o sì so àmùrè éfódì tí wọ́n hun* náà mọ́ ìbàdí rẹ̀ pinpin.+
7 Lẹ́yìn náà, ó wọ aṣọ+ fún un, ó de ọ̀já+ mọ́ ọn, ó wọ aṣọ àwọ̀lékè tí kò lápá+ fún un, ó wọ éfódì+ fún un, ó sì fi àmùrè éfódì tí wọ́n hun pọ̀*+ dè é mọ́ ọn pinpin.