Léfítíkù 8:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Mósè mú lára òróró àfiyanni,+ ó sì mú lára ẹ̀jẹ̀ tó wà lórí pẹpẹ, ó wọ́n ọn sára Áárónì àti aṣọ rẹ̀ àti sára àwọn ọmọ rẹ̀ àti aṣọ àwọn ọmọ rẹ̀ tó wà pẹ̀lú rẹ̀. Bó ṣe sọ Áárónì àti aṣọ rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ̀+ àti aṣọ wọn+ di mímọ́ nìyẹn.
30 Mósè mú lára òróró àfiyanni,+ ó sì mú lára ẹ̀jẹ̀ tó wà lórí pẹpẹ, ó wọ́n ọn sára Áárónì àti aṣọ rẹ̀ àti sára àwọn ọmọ rẹ̀ àti aṣọ àwọn ọmọ rẹ̀ tó wà pẹ̀lú rẹ̀. Bó ṣe sọ Áárónì àti aṣọ rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ̀+ àti aṣọ wọn+ di mímọ́ nìyẹn.