7Ní ọjọ́ tí Mósè to àgọ́ ìjọsìn+ náà tán, ó fòróró yàn án,+ ó sì yà á sí mímọ́ pẹ̀lú gbogbo ohun tó wà níbẹ̀, pẹpẹ àti gbogbo ohun èlò rẹ̀.+ Lẹ́yìn tó fòróró yan nǹkan wọ̀nyí, tó sì sọ wọ́n di mímọ́,+
15 Ní ọjọ́ tí wọ́n to+ àgọ́ ìjọsìn, ìkùukùu* bo àgọ́ ìjọsìn náà, ìyẹn àgọ́ Ẹ̀rí, àmọ́ láti ìrọ̀lẹ́ títí di àárọ̀,+ ohun tó rí bí iná wà lórí àgọ́ ìjọsìn náà.