Ẹ́kísódù 26:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “Kí o fi igi bọn-ọ̀n-ní ṣe àwọn férémù+ àgọ́ ìjọsìn náà, kí wọ́n wà ní òró.+