Nọ́ńbà 9:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ní ọjọ́ tí wọ́n to+ àgọ́ ìjọsìn, ìkùukùu* bo àgọ́ ìjọsìn náà, ìyẹn àgọ́ Ẹ̀rí, àmọ́ láti ìrọ̀lẹ́ títí di àárọ̀,+ ohun tó rí bí iná wà lórí àgọ́ ìjọsìn náà. Ìfihàn 15:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Èéfín sì kún ibi mímọ́ torí ògo Ọlọ́run+ àti agbára rẹ̀, ẹnì kankan ò sì lè wọnú ibi mímọ́ náà títí tí ìyọnu méje+ àwọn áńgẹ́lì méje náà fi parí.
15 Ní ọjọ́ tí wọ́n to+ àgọ́ ìjọsìn, ìkùukùu* bo àgọ́ ìjọsìn náà, ìyẹn àgọ́ Ẹ̀rí, àmọ́ láti ìrọ̀lẹ́ títí di àárọ̀,+ ohun tó rí bí iná wà lórí àgọ́ ìjọsìn náà.
8 Èéfín sì kún ibi mímọ́ torí ògo Ọlọ́run+ àti agbára rẹ̀, ẹnì kankan ò sì lè wọnú ibi mímọ́ náà títí tí ìyọnu méje+ àwọn áńgẹ́lì méje náà fi parí.