-
Ìsíkíẹ́lì 16:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Nígbà ìbí rẹ, ní ọjọ́ tí wọ́n bí ọ, wọn ò gé ìwọ́ rẹ, wọn ò fi omi wẹ̀ ọ́ kí ara rẹ lè mọ́, wọn ò fi iyọ̀ pa ọ́ lára, wọn ò sì fi aṣọ wé ọ.
-