Ẹ́kísódù 29:45 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Èmi yóò máa gbé láàárín* àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, èmi yóò sì jẹ́ Ọlọ́run wọn.+ Diutarónómì 7:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Torí èèyàn mímọ́ lẹ jẹ́ fún Jèhófà Ọlọ́run yín, Jèhófà Ọlọ́run yín sì ti yàn yín kí ẹ lè di èèyàn rẹ̀, ohun ìní rẹ̀ pàtàkì,* nínú gbogbo èèyàn tó wà láyé.+ 2 Sámúẹ́lì 7:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 O fìdí àwọn èèyàn rẹ Ísírẹ́lì múlẹ̀ láti máa jẹ́ àwọn èèyàn rẹ títí lọ;+ ìwọ Jèhófà sì di Ọlọ́run wọn.+ Sáàmù 33:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Aláyọ̀ ni orílẹ̀-èdè tí Jèhófà jẹ́ Ọlọ́run rẹ̀,+Àwọn èèyàn tí ó ti yàn láti jẹ́ ohun ìní rẹ̀.+
6 Torí èèyàn mímọ́ lẹ jẹ́ fún Jèhófà Ọlọ́run yín, Jèhófà Ọlọ́run yín sì ti yàn yín kí ẹ lè di èèyàn rẹ̀, ohun ìní rẹ̀ pàtàkì,* nínú gbogbo èèyàn tó wà láyé.+
24 O fìdí àwọn èèyàn rẹ Ísírẹ́lì múlẹ̀ láti máa jẹ́ àwọn èèyàn rẹ títí lọ;+ ìwọ Jèhófà sì di Ọlọ́run wọn.+