Ìṣe 7:18, 19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 títí ọba míì fi jẹ ní Íjíbítì, ẹni tí kò mọ Jósẹ́fù.+ 19 Ẹni yìí lo ọgbọ́n àrékérekè fún àwọn èèyàn wa, ó sì fipá mú àwọn bàbá láti pa àwọn ọmọ wọn jòjòló tì, kí wọ́n má bàa wà láàyè.+
18 títí ọba míì fi jẹ ní Íjíbítì, ẹni tí kò mọ Jósẹ́fù.+ 19 Ẹni yìí lo ọgbọ́n àrékérekè fún àwọn èèyàn wa, ó sì fipá mú àwọn bàbá láti pa àwọn ọmọ wọn jòjòló tì, kí wọ́n má bàa wà láàyè.+