Ẹ́kísódù 6:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ámúrámù wá fi Jókébédì àbúrò bàbá rẹ̀ ṣe aya.+ Jókébédì sì bí Áárónì àti Mósè fún un.+ Ọjọ́ ayé Ámúrámù jẹ́ ọdún mẹ́tàdínlógóje (137). Nọ́ńbà 26:59 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 59 Orúkọ ìyàwó Ámúrámù sì ni Jókébédì,+ ọmọ Léfì, tí ìyàwó rẹ̀ bí fún un ní Íjíbítì. Ó wá bí Áárónì àti Mósè àti Míríámù+ arábìnrin wọn fún Ámúrámù.
20 Ámúrámù wá fi Jókébédì àbúrò bàbá rẹ̀ ṣe aya.+ Jókébédì sì bí Áárónì àti Mósè fún un.+ Ọjọ́ ayé Ámúrámù jẹ́ ọdún mẹ́tàdínlógóje (137).
59 Orúkọ ìyàwó Ámúrámù sì ni Jókébédì,+ ọmọ Léfì, tí ìyàwó rẹ̀ bí fún un ní Íjíbítì. Ó wá bí Áárónì àti Mósè àti Míríámù+ arábìnrin wọn fún Ámúrámù.