-
Ẹ́kísódù 7:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Àwọn ẹja inú odò Náílì yóò kú, odò Náílì yóò máa rùn, àwọn ará Íjíbítì ò sì ní lè mu omi odò Náílì rárá.”’”
-
-
Ẹ́kísódù 7:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Gbogbo àwọn ará Íjíbítì wá ń gbẹ́lẹ̀ kiri yí odò Náílì ká kí wọ́n lè rí omi mu, torí wọn ò lè mu omi odò Náílì rárá.
-