Sáàmù 78:48 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 48 Ó fi yìnyín pa àwọn ẹran akẹ́rù wọn,+Ó sì sán ààrá* pa àwọn ẹran ọ̀sìn wọn.