Ẹ́kísódù 9:31, 32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ọ̀gbọ̀ àti ọkà bálì ti run, torí pé ọkà bálì wà nínú ṣírí, ọ̀gbọ̀ sì ti yọ òdòdó. 32 Àmọ́ kò sóhun tó ṣe àlìkámà* àti ọkà sípẹ́ẹ̀tì torí wọ́n máa ń pẹ́ so.*
31 Ọ̀gbọ̀ àti ọkà bálì ti run, torí pé ọkà bálì wà nínú ṣírí, ọ̀gbọ̀ sì ti yọ òdòdó. 32 Àmọ́ kò sóhun tó ṣe àlìkámà* àti ọkà sípẹ́ẹ̀tì torí wọ́n máa ń pẹ́ so.*