Ẹ́kísódù 7:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ní tèmi, màá jẹ́ kí ọkàn Fáráò le,+ màá sì ṣe iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu tó pọ̀ ní ilẹ̀ Íjíbítì.+ Ẹ́kísódù 11:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Mósè àti Áárónì ṣe gbogbo iṣẹ́ ìyanu yìí níwájú Fáráò,+ àmọ́ Jèhófà jẹ́ kí ọkàn Fáráò le, kò sì jẹ́ kí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kúrò ní ilẹ̀ rẹ̀.+ Róòmù 9:17, 18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Nítorí Ìwé Mímọ́ sọ fún Fáráò pé: “Ìdí tí mo fi jẹ́ kí o máa wà nìṣó ni pé: kí n lè fi agbára mi hàn nípasẹ̀ rẹ àti pé kí a lè ròyìn orúkọ mi ní gbogbo ayé.”+ 18 Torí náà, ẹni tó bá wù ú ló ń ṣàánú, ẹni tó bá sì wù ú ló ń jẹ́ kó di olóríkunkun.+
10 Mósè àti Áárónì ṣe gbogbo iṣẹ́ ìyanu yìí níwájú Fáráò,+ àmọ́ Jèhófà jẹ́ kí ọkàn Fáráò le, kò sì jẹ́ kí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kúrò ní ilẹ̀ rẹ̀.+
17 Nítorí Ìwé Mímọ́ sọ fún Fáráò pé: “Ìdí tí mo fi jẹ́ kí o máa wà nìṣó ni pé: kí n lè fi agbára mi hàn nípasẹ̀ rẹ àti pé kí a lè ròyìn orúkọ mi ní gbogbo ayé.”+ 18 Torí náà, ẹni tó bá wù ú ló ń ṣàánú, ẹni tó bá sì wù ú ló ń jẹ́ kó di olóríkunkun.+