-
Ìṣe 7:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Nígbà tó tajú kán rí ọ̀kan lára wọn tí ará Íjíbítì kan ń hùwà àìdáa sí, ó gbèjà rẹ̀, ó sì bá ẹni tí wọ́n ń ṣàìdáa sí náà gbẹ̀san, ó pa ará Íjíbítì náà.
-