-
Ìṣe 7:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Lọ́jọ́ kejì, ó yọ sí wọn nígbà tí wọ́n ń jà, ó sì fẹ́ bá wọn parí ìjà ní àlàáfíà, ó sọ pé: ‘Ẹ̀yin èèyàn, arákùnrin ni yín. Kí ló dé tí ẹ̀ ń hùwà àìdáa sí ara yín?’
-