-
Ẹ́kísódù 10:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Àwọn ẹran ọ̀sìn wa náà máa bá wa lọ. A ò ní jẹ́ kí ẹran* kankan ṣẹ́ kù, torí a máa lò lára wọn láti jọ́sìn Jèhófà Ọlọ́run wa, a ò sì mọ ohun tí a máa fi rúbọ sí Jèhófà àfi tí a bá débẹ̀.”
-