Ẹ́kísódù 12:24, 25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 “Kí ẹ máa pa àjọ̀dún yìí mọ́, ó ti di àṣẹ fún ẹ̀yin àti àwọn ọmọ yín títí láé.+ 25 Tí ẹ bá sì dé ilẹ̀ tí Jèhófà yóò fún yín bó ṣe sọ, kí ẹ máa ṣe àjọyọ̀ yìí.+
24 “Kí ẹ máa pa àjọ̀dún yìí mọ́, ó ti di àṣẹ fún ẹ̀yin àti àwọn ọmọ yín títí láé.+ 25 Tí ẹ bá sì dé ilẹ̀ tí Jèhófà yóò fún yín bó ṣe sọ, kí ẹ máa ṣe àjọyọ̀ yìí.+