-
Ẹ́kísódù 6:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Nígbà tó yá, Mósè jíṣẹ́ yìí fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, àmọ́ wọn ò fetí sí Mósè torí wọ́n ti rẹ̀wẹ̀sì àti pé ìyà ń jẹ wọ́n gan-an lóko ẹrú.+
-