Ẹ́kísódù 3:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Jèhófà sì sọ pé: “Mo ti rí ìyà tó ń jẹ àwọn èèyàn mi ní Íjíbítì, mo sì ti gbọ́ igbe wọn torí àwọn tó ń fipá kó wọn ṣiṣẹ́; mo mọ̀ dáadáa pé wọ́n ń jẹ̀rora.+ 1 Àwọn Ọba 8:51 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 51 (nítorí èèyàn rẹ àti ogún rẹ ni wọ́n,+ àwọn tí o mú jáde kúrò ní Íjíbítì,+ láti ibi iná tí a fi ń yọ́ irin).+
7 Jèhófà sì sọ pé: “Mo ti rí ìyà tó ń jẹ àwọn èèyàn mi ní Íjíbítì, mo sì ti gbọ́ igbe wọn torí àwọn tó ń fipá kó wọn ṣiṣẹ́; mo mọ̀ dáadáa pé wọ́n ń jẹ̀rora.+
51 (nítorí èèyàn rẹ àti ogún rẹ ni wọ́n,+ àwọn tí o mú jáde kúrò ní Íjíbítì,+ láti ibi iná tí a fi ń yọ́ irin).+