-
Jẹ́nẹ́sísì 50:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Ẹni àádọ́fà (110) ọdún ni Jósẹ́fù nígbà tó kú, wọ́n sì tọ́jú òkú rẹ̀ kó má bàa jẹrà,+ wọ́n wá gbé e sínú pósí ní ilẹ̀ Íjíbítì.
-