ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 28:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Wò ó! Jèhófà wà lókè rẹ̀, ó sì sọ pé:

      “Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run Ábúráhámù bàbá rẹ àti Ọlọ́run Ísákì.+ Ìwọ àti àtọmọdọ́mọ*+ rẹ ni màá fún ní ilẹ̀ tí o dùbúlẹ̀ sí yìí.

  • Jẹ́nẹ́sísì 32:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Lẹ́yìn náà, Jékọ́bù sọ pé: “Ọlọ́run Ábúráhámù bàbá mi àti Ọlọ́run Ísákì bàbá mi, Jèhófà, ìwọ tí ò ń sọ fún mi pé, ‘Pa dà sí ilẹ̀ rẹ àti sọ́dọ̀ àwọn mọ̀lẹ́bí rẹ, màá sì ṣe dáadáa sí ọ,’+

  • Mátíù 22:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 ‘Èmi ni Ọlọ́run Ábúráhámù, Ọlọ́run Ísákì àti Ọlọ́run Jékọ́bù’?+ Kì í ṣe Ọlọ́run àwọn òkú, àmọ́ ó jẹ́ Ọlọ́run àwọn alààyè.”+

  • Ìṣe 7:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 ‘Èmi ni Ọlọ́run àwọn baba ńlá rẹ, Ọlọ́run Ábúráhámù àti ti Ísákì àti ti Jékọ́bù.’+ Mósè bẹ̀rẹ̀ sí í gbọ̀n, kò sì gbójúgbóyà láti sọ pé òun fẹ́ wádìí sí i.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́