-
Ẹ́kísódù 15:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Lẹ́yìn náà, Mósè darí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kúrò ní Òkun Pupa, wọ́n sì lọ sí aginjù Ṣúrì. Wọ́n rin ìrìn ọjọ́ mẹ́ta ní aginjù, àmọ́ wọn ò rí omi.
-