-
Ẹ́kísódù 19:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Lọ bá àwọn èèyàn náà, kí o sọ wọ́n di mímọ́ lónìí àti lọ́la, kí wọ́n sì fọ aṣọ wọn.