Ẹ́kísódù 16:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ẹ kíyè sí i pé Jèhófà ti fún yín ní Sábáàtì.+ Ìdí nìyẹn tó fi fún yín ní oúnjẹ ọjọ́ méjì ní ọjọ́ kẹfà. Kí kálukú dúró sí ibi tó bá wà; ẹnikẹ́ni ò gbọ́dọ̀ kúrò ní agbègbè rẹ̀ ní ọjọ́ keje.” Ẹ́kísódù 34:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 “Ọjọ́ mẹ́fà ni kí ẹ fi ṣiṣẹ́, àmọ́ kí ẹ sinmi* ní ọjọ́ keje.+ Kódà, nígbà ìtúlẹ̀ àti ìkórè, kí ẹ sinmi.
29 Ẹ kíyè sí i pé Jèhófà ti fún yín ní Sábáàtì.+ Ìdí nìyẹn tó fi fún yín ní oúnjẹ ọjọ́ méjì ní ọjọ́ kẹfà. Kí kálukú dúró sí ibi tó bá wà; ẹnikẹ́ni ò gbọ́dọ̀ kúrò ní agbègbè rẹ̀ ní ọjọ́ keje.”
21 “Ọjọ́ mẹ́fà ni kí ẹ fi ṣiṣẹ́, àmọ́ kí ẹ sinmi* ní ọjọ́ keje.+ Kódà, nígbà ìtúlẹ̀ àti ìkórè, kí ẹ sinmi.