Diutarónómì 5:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “‘Bọlá fún bàbá rẹ àti ìyá rẹ,+ bí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ṣe pa á láṣẹ fún ọ gẹ́lẹ́, kí ẹ̀mí rẹ lè gùn, kí nǹkan sì lè máa lọ dáadáa fún ọ lórí ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa fún ọ.+ Mátíù 15:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Bí àpẹẹrẹ, Ọlọ́run sọ pé, ‘Bọlá fún bàbá rẹ àti ìyá rẹ’+ àti pé, ‘Kí ẹ pa ẹni tó bá sọ̀rọ̀ òdì sí* bàbá tàbí ìyá rẹ̀.’+ Éfésù 6:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Bọlá fún bàbá rẹ àti ìyá rẹ,”+ èyí ni àṣẹ kìíní pẹ̀lú ìlérí: 3 “Kí nǹkan lè máa lọ dáadáa fún ọ,* kí o sì lè pẹ́ láyé.”
16 “‘Bọlá fún bàbá rẹ àti ìyá rẹ,+ bí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ṣe pa á láṣẹ fún ọ gẹ́lẹ́, kí ẹ̀mí rẹ lè gùn, kí nǹkan sì lè máa lọ dáadáa fún ọ lórí ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa fún ọ.+
4 Bí àpẹẹrẹ, Ọlọ́run sọ pé, ‘Bọlá fún bàbá rẹ àti ìyá rẹ’+ àti pé, ‘Kí ẹ pa ẹni tó bá sọ̀rọ̀ òdì sí* bàbá tàbí ìyá rẹ̀.’+
2 “Bọlá fún bàbá rẹ àti ìyá rẹ,”+ èyí ni àṣẹ kìíní pẹ̀lú ìlérí: 3 “Kí nǹkan lè máa lọ dáadáa fún ọ,* kí o sì lè pẹ́ láyé.”