ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 15:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Jagunjagun tó lágbára ni Jèhófà.+ Jèhófà ni orúkọ rẹ̀.+

  • Sáàmù 96:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Ẹ fún Jèhófà ní ògo tí ó yẹ orúkọ rẹ̀;+

      Ẹ mú ẹ̀bùn dání wá sínú àwọn àgbàlá rẹ̀.

  • Sáàmù 135:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Jèhófà, orúkọ rẹ wà títí láé.

      Jèhófà, òkìkí rẹ yóò máa kàn* láti ìran dé ìran.+

  • Hósíà 12:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun+ ni,

      Jèhófà sì ni orúkọ tí a fi ń rántí rẹ̀.*+

  • Jòhánù 17:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Mo ti jẹ́ kí wọ́n mọ orúkọ rẹ, màá sì jẹ́ kí wọ́n mọ̀ ọ́n,+ kí ìfẹ́ tí o ní fún mi lè wà nínú wọn, kí n sì wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú wọn.”+

  • Róòmù 10:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Nítorí “gbogbo ẹni tó bá ń ké pe orúkọ Jèhófà* yóò rí ìgbàlà.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́