Jóṣúà 24:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “Torí náà, ẹ bẹ̀rù Jèhófà, kí ẹ sì máa fi ìwà títọ́* àti òótọ́ inú* sìn ín,+ kí ẹ mú àwọn ọlọ́run tí àwọn baba ńlá yín sìn ní òdìkejì Odò* àti ní Íjíbítì kúrò,+ kí ẹ sì máa sin Jèhófà. Jóòbù 28:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ó sì sọ fún èèyàn pé: ‘Wò ó! Ìbẹ̀rù Jèhófà ni ọgbọ́n,+Yíyẹra fún ìwà burúkú sì ni òye.’”+ Òwe 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìbẹ̀rù* Jèhófà ni ìbẹ̀rẹ̀ ìmọ̀.+ Àwọn òmùgọ̀ ni kì í ka ọgbọ́n àti ìbáwí sí.+
14 “Torí náà, ẹ bẹ̀rù Jèhófà, kí ẹ sì máa fi ìwà títọ́* àti òótọ́ inú* sìn ín,+ kí ẹ mú àwọn ọlọ́run tí àwọn baba ńlá yín sìn ní òdìkejì Odò* àti ní Íjíbítì kúrò,+ kí ẹ sì máa sin Jèhófà.