-
Léfítíkù 20:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 “‘Tí ọkùnrin kan bá bá ẹranko lò pọ̀, ẹ gbọ́dọ̀ pa á, kí ẹ sì pa ẹranko náà.+
-
-
Diutarónómì 27:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 “‘Ègún ni fún ẹni tó bá bá ẹranko èyíkéyìí lò pọ̀.’+ (Kí gbogbo èèyàn sì sọ pé, ‘Àmín!’)
-