Diutarónómì 16:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Kí kálukú yín mú ẹ̀bùn wá bí Jèhófà Ọlọ́run yín bá ṣe bù kún yín tó.+