-
Jóṣúà 5:13, 14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Nígbà tí Jóṣúà wà nítòsí Jẹ́ríkò, ó gbójú sókè, ó sì rí ọkùnrin kan+ tó dúró níwájú rẹ̀, tó fa idà yọ.+ Jóṣúà lọ bá a, ó sì bi í pé: “Ṣé tiwa lò ń ṣe ni, àbí tàwọn ọ̀tá wa?” 14 Ó fèsì pé: “Rárá o, mo wá gẹ́gẹ́ bí olórí* àwọn ọmọ ogun Jèhófà.”+ Ni Jóṣúà bá dojú bolẹ̀, ó sì wólẹ̀, ó sọ fún un pé: “Kí ni olúwa mi fẹ́ sọ fún ìránṣẹ́ rẹ̀?”
-