-
Àwọn Onídàájọ́ 1:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Nígbà tí Júdà lọ, Jèhófà fi àwọn ọmọ Kénáánì àti àwọn Pérísì lé wọn lọ́wọ́,+ wọ́n sì ṣẹ́gun ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) ọkùnrin ní Bésékì.
-
-
Àwọn Onídàájọ́ 11:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì wá fi Síhónì àti gbogbo àwọn èèyàn rẹ̀ lé Ísírẹ́lì lọ́wọ́, torí náà wọ́n ṣẹ́gun wọn, Ísírẹ́lì sì gba gbogbo ilẹ̀ àwọn Ámórì tó ń gbé ilẹ̀ náà.+
-