-
Ẹ́kísódù 38:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Lẹ́yìn ìyẹn, ó ṣe gbogbo ohun èlò pẹpẹ náà, àwọn korobá, àwọn ṣọ́bìrì, àwọn abọ́, àwọn àmúga àti àwọn ìkóná. Bàbà ló fi ṣe gbogbo ohun èlò rẹ̀.
-
-
Ẹ́kísódù 38:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Bàbà tí wọ́n fi ṣe ọrẹ* jẹ́ àádọ́rin (70) tálẹ́ńtì àti ẹgbẹ̀rún méjì ó lé ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (2,400) ṣékélì.
-