Jẹ́nẹ́sísì 14:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Lẹ́yìn náà, ọkùnrin kan tó sá àsálà wá sọ fún Ábúrámù tó jẹ́ Hébérù. Nígbà yẹn, ó ń gbé* láàárín àwọn igi ńlá Mámúrè ọmọ Ámórì,+ arákùnrin Éṣíkólì àti Ánérì.+ Àwọn ọkùnrin yìí máa ń ran Ábúrámù lọ́wọ́.
13 Lẹ́yìn náà, ọkùnrin kan tó sá àsálà wá sọ fún Ábúrámù tó jẹ́ Hébérù. Nígbà yẹn, ó ń gbé* láàárín àwọn igi ńlá Mámúrè ọmọ Ámórì,+ arákùnrin Éṣíkólì àti Ánérì.+ Àwọn ọkùnrin yìí máa ń ran Ábúrámù lọ́wọ́.