Jẹ́nẹ́sísì 3:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Torí náà, ó lé ọkùnrin náà jáde, ó sì fi àwọn kérúbù+ àti idà oníná tó ń yí láìdáwọ́ dúró sí ìlà oòrùn ọgbà Édẹ́nì, kí wọ́n lè máa ṣọ́ ọ̀nà tó lọ síbi igi ìyè náà. Sáàmù 99:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 99 Jèhófà ti di Ọba.+ Kí jìnnìjìnnì bá àwọn èèyàn. Ó gúnwà lórí* àwọn kérúbù.+ Kí ayé mì tìtì.
24 Torí náà, ó lé ọkùnrin náà jáde, ó sì fi àwọn kérúbù+ àti idà oníná tó ń yí láìdáwọ́ dúró sí ìlà oòrùn ọgbà Édẹ́nì, kí wọ́n lè máa ṣọ́ ọ̀nà tó lọ síbi igi ìyè náà.