-
Ẹ́kísódù 39:33, 34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Lẹ́yìn náà, wọ́n gbé àgọ́ ìjọsìn+ náà wá sọ́dọ̀ Mósè, àgọ́ náà+ àti gbogbo ohun èlò rẹ̀: àwọn ìkọ́ rẹ̀,+ àwọn férémù rẹ̀,+ àwọn ọ̀pá gbọọrọ rẹ̀+ àti àwọn òpó rẹ̀ àti àwọn ìtẹ́lẹ̀ oníhò rẹ̀;+ 34 ìbòrí rẹ̀ tí wọ́n fi awọ àgbò tí wọ́n pa láró pupa ṣe,+ ìbòrí rẹ̀ tí wọ́n fi awọ séálì ṣe, aṣọ tí wọ́n máa ta sí ẹnu ọ̀nà;+
-