Léfítíkù 4:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Kí àlùfáà fi ìka rẹ̀ mú lára ẹ̀jẹ̀ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ náà, kó fi sára àwọn ìwo+ pẹpẹ ẹbọ sísun, kó sì da ẹ̀jẹ̀ tó kù sí ìsàlẹ̀ pẹpẹ ẹbọ sísun.+
25 Kí àlùfáà fi ìka rẹ̀ mú lára ẹ̀jẹ̀ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ náà, kó fi sára àwọn ìwo+ pẹpẹ ẹbọ sísun, kó sì da ẹ̀jẹ̀ tó kù sí ìsàlẹ̀ pẹpẹ ẹbọ sísun.+