Ẹ́kísódù 29:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 “Kí o yọ ọ̀rá lára àgbò náà, kí o gé ìrù rẹ̀ tó lọ́ràá, ọ̀rá tó bo ìfun, àmọ́ tó wà lára ẹ̀dọ̀, kíndìnrín méjèèjì àti ọ̀rá tó wà lára wọn,+ pẹ̀lú ẹsẹ̀ rẹ̀ ọ̀tún, torí ó jẹ́ àgbò àfiyanni.+
22 “Kí o yọ ọ̀rá lára àgbò náà, kí o gé ìrù rẹ̀ tó lọ́ràá, ọ̀rá tó bo ìfun, àmọ́ tó wà lára ẹ̀dọ̀, kíndìnrín méjèèjì àti ọ̀rá tó wà lára wọn,+ pẹ̀lú ẹsẹ̀ rẹ̀ ọ̀tún, torí ó jẹ́ àgbò àfiyanni.+