-
Léfítíkù 7:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 “‘Òfin ẹbọ ìrẹ́pọ̀+ tí ẹnì kan bá mú wá fún Jèhófà nìyí:
-
-
Léfítíkù 7:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Kó mú ọ̀kan lára ọrẹ kọ̀ọ̀kan wá nínú rẹ̀ láti fi ṣe ìpín mímọ́ fún Jèhófà; yóò di ti àlùfáà tó wọ́n ẹ̀jẹ̀ ẹbọ ìrẹ́pọ̀.+
-