Léfítíkù 8:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Kí ẹ wà ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé tọ̀sántòru fún ọjọ́ méje,+ kí ẹ sì ṣe ohun tí Jèhófà ní kí ẹ ṣe,+ kí ẹ má bàa kú; torí àṣẹ tí mo gbà ni.”
35 Kí ẹ wà ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé tọ̀sántòru fún ọjọ́ méje,+ kí ẹ sì ṣe ohun tí Jèhófà ní kí ẹ ṣe,+ kí ẹ má bàa kú; torí àṣẹ tí mo gbà ni.”