-
Léfítíkù 8:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Mósè ṣe ohun tí Jèhófà pa láṣẹ fún un gẹ́lẹ́, àpéjọ náà sì kóra jọ sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé.