-
Ẹ́kísódù 30:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 “Kí o ta òróró náà sí àgọ́ ìpàdé+ àti àpótí Ẹ̀rí,
-
-
Ẹ́kísódù 30:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 pẹpẹ ẹbọ sísun àti gbogbo ohun èlò rẹ̀, pẹ̀lú bàsíà àti ẹsẹ̀ rẹ̀.
-
-
Léfítíkù 8:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Lẹ́yìn náà, ó wọ́n lára rẹ̀ sórí pẹpẹ lẹ́ẹ̀méje, ó sì fòróró yan pẹpẹ àti gbogbo ohun èlò rẹ̀ àti bàsíà àti ẹsẹ̀ rẹ̀ láti yà wọ́n sí mímọ́.
-