-
2 Kíróníkà 24:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Lẹ́yìn náà, wọ́n kéde káàkiri Júdà àti Jerúsálẹ́mù pé kí wọ́n mú owó orí mímọ́+ tí Mósè ìránṣẹ́ Ọlọ́run tòótọ́ bù lé Ísírẹ́lì ní aginjù, wá fún Jèhófà.
-